Ẹkisodu 38:4 BM

4 Ó fi idẹ ṣe ayanran ààrò kan fún pẹpẹ náà, ó ṣe é mọ́ abẹ́ ìgbátí rẹ̀, ayanran náà sì bò ó dé agbede meji sí ìsàlẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:4 ni o tọ