Ẹkisodu 39:15 BM

15 Wọ́n fi ojúlówó wúrà ṣe ẹ̀wọ̀n tí a lọ́pọ̀ gẹ́gẹ́ bí okùn fún ìgbàyà náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 39

Wo Ẹkisodu 39:15 ni o tọ