Ẹkisodu 39:18 BM

18 Wọ́n mú etí kinni keji ẹ̀wọ̀n wúrà mejeeji, wọ́n so wọ́n mọ́ ojú ìdè wúrà ara ìgbàyà náà, wọ́n sì so wọ́n mọ́ èjìká efodu náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 39

Wo Ẹkisodu 39:18 ni o tọ