20 Wọ́n sì da òrùka wúrà meji mìíràn, wọ́n dè wọ́n mọ́ ìsàlẹ̀ èjìká efodu náà níwájú, lókè ibi tí ó ti so pọ̀ mọ́ àmùrè rẹ̀.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 39
Wo Ẹkisodu 39:20 ni o tọ