38 Bẹ́ẹ̀ sì ni pẹpẹ wúrà náà, ati òróró ìyàsímímọ́, ati turari olóòórùn dídùn, ati aṣọ títa fún ìlẹ̀kùn àgọ́ mímọ́ náà;
Ka pipe ipin Ẹkisodu 39
Wo Ẹkisodu 39:38 ni o tọ