43 Mose wo gbogbo iṣẹ́ náà, ó rí i pé wọ́n ṣe é gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pa á láṣẹ, Mose sì súre fún wọn.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 39
Wo Ẹkisodu 39:43 ni o tọ