Ẹkisodu 39:6 BM

6 Wọ́n tọ́jú àwọn òkúta onikisi, wọ́n jó wọn mọ́ ojú ìtẹ́lẹ̀ wúrà, wọ́n kọ orúkọ àwọn ẹ̀yà Israẹli sí ara wọn, bí wọ́n ti máa ń kọ orúkọ sí ara òrùka èdìdì.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 39

Wo Ẹkisodu 39:6 ni o tọ