9 Bákan náà ni òòró ati ìbú aṣọ ìgbàyà náà, ìṣẹ́po aṣọ meji ni wọ́n sì rán pọ̀. Ìká kan ni òòró rẹ̀, ìká kan náà sì ni ìbú rẹ̀.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 39
Wo Ẹkisodu 39:9 ni o tọ