Ẹkisodu 4:15 BM

15 O óo máa bá a sọ̀rọ̀, o óo sì fi ọ̀rọ̀ sí i lẹ́nu. N óo gbàkóso ẹnu rẹ ati ẹnu rẹ̀; n óo sì kọ yín ní ohun tí ẹ óo ṣe.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 4

Wo Ẹkisodu 4:15 ni o tọ