19 OLUWA sọ fún Mose ní Midiani pé, “Pada lọ sí Ijipti, nítorí pé gbogbo àwọn tí wọn ń lépa ẹ̀mí rẹ ti kú tán.”
Ka pipe ipin Ẹkisodu 4
Wo Ẹkisodu 4:19 ni o tọ