Ẹkisodu 4:4 BM

4 Ṣugbọn OLUWA sọ fún Mose pé, “Na ọwọ́ rẹ, kí o mú un ní ìrù.” Mose nawọ́ mú un, ejò náà sì pada di ọ̀pá ní ọwọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 4

Wo Ẹkisodu 4:4 ni o tọ