Ẹkisodu 40:10 BM

10 Ta òróró sí ara pẹpẹ ẹbọ sísun pẹlu, ati sí ara gbogbo àwọn ohun èlò rẹ̀, kí o ya pẹpẹ náà sí mímọ́, pẹpẹ náà yóo sì di ohun mímọ́ jùlọ.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 40

Wo Ẹkisodu 40:10 ni o tọ