Ẹkisodu 40:20 BM

20 Ó kó àwọn tabili òkúta mejeeji sinu àpótí ẹ̀rí náà, ó ti àwọn ọ̀pá àpótí náà bọ inú àwọn òrùka rẹ̀, ó sì fi ìdérí rẹ̀ dé e lórí.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 40

Wo Ẹkisodu 40:20 ni o tọ