Ẹkisodu 40:29 BM

29 Ó gbé pẹpẹ ẹbọ sísun kalẹ̀ níbi ẹnu ọ̀nà àgọ́ náà, ó sì rú ẹbọ sísun ati ẹbọ ohun jíjẹ gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún un.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 40

Wo Ẹkisodu 40:29 ni o tọ