Ẹkisodu 5:20 BM

20 Bí wọ́n ti ń ti ọ̀dọ̀ Farao bọ̀, wọ́n lọ sọ́dọ̀ Mose ati Aaroni tí wọ́n dúró dè wọ́n, wọ́n sì sọ fún wọn pé,

Ka pipe ipin Ẹkisodu 5

Wo Ẹkisodu 5:20 ni o tọ