22 Mose bá tún yipada sí OLUWA, ó ní, “OLUWA, kí ló dé tí o fi ṣe ibi sí àwọn eniyan wọnyi? Kí ló dé tí o fi rán mi sí wọn?
Ka pipe ipin Ẹkisodu 5
Wo Ẹkisodu 5:22 ni o tọ