Ẹkisodu 6:12 BM

12 Ṣugbọn Mose dá OLUWA lóhùn pé, “Àwọn eniyan Israẹli gan-an kò gbọ́ tèmi, báwo ni Farao yóo ṣe gbọ́, èmi akólòlò lásánlàsàn.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:12 ni o tọ