Ẹkisodu 6:14 BM

14 Èyí ni àkọsílẹ̀ àwọn olórí olórí ninu ìdílé wọn: Reubẹni, àkọ́bí Jakọbu bí ọmọkunrin mẹrin: Hanoku, Palu, Hesironi ati Karimi; àwọn ni olórí àwọn ìdílé ẹ̀yà Reubẹni.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:14 ni o tọ