16 Lefi bí ọmọ mẹta: Geriṣoni, Kohati ati Merari; àwọn ni olórí àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi. Ọdún mẹtadinlogoje (137) ni Lefi gbé láyé.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 6
Wo Ẹkisodu 6:16 ni o tọ