Ẹkisodu 6:18 BM

18 Kohati bí ọmọ mẹrin: Amramu, Iṣari, Heburoni ati Usieli. Ọdún mẹtalelaadoje (133) ni Kohati gbé láyé.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:18 ni o tọ