20 Amramu fẹ́ Jokebedi, arabinrin baba rẹ̀. Jokebedi sì bí Aaroni ati Mose fún un. Ọdún mẹtadinlogoje (137) ni Amramu gbé láyé.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 6
Wo Ẹkisodu 6:20 ni o tọ