Ẹkisodu 6:23 BM

23 Aaroni fẹ́ Eliṣeba ọmọbinrin Aminadabu tíí ṣe arabinrin Naṣoni. Àwọn ọmọ tí ó bí fún un nìwọ̀nyí: Nadabu, Abihu, Eleasari, ati Itamari.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:23 ni o tọ