25 Eleasari ọmọ Aaroni fẹ́ ọ̀kan ninu àwọn ọmọbinrin Putieli; ó sì bí Finehasi fún un; àwọn ni olórí àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 6
Wo Ẹkisodu 6:25 ni o tọ