Ẹkisodu 6:29 BM

29 OLUWA sọ fún un pé, “Èmi ni OLUWA, sọ gbogbo ohun tí mo rán ọ fún Farao, ọba Ijipti.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:29 ni o tọ