Ẹkisodu 6:3 BM

3 Mo fara han Abrahamu, Isaaki, ati Jakọbu gẹ́gẹ́ bí Ọlọrun Olodumare, ṣugbọn n kò farahàn wọ́n gẹ́gẹ́ bí OLUWA tíí ṣe orúkọ mi gan-an.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:3 ni o tọ