Ẹkisodu 7:11 BM

11 Farao bá pe gbogbo àwọn ọlọ́gbọ́n, ati àwọn oṣó, ati àwọn pidánpidán tí wọ́n wà ní ilẹ̀ Ijipti, àwọn náà pa idán, wọ́n ṣe bí Aaroni ti ṣe.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 7

Wo Ẹkisodu 7:11 ni o tọ