17 OLUWA wí pé ohun tí o óo fi mọ̀ pé òun ni OLUWA nìyí: n óo fi ọ̀pá tí ó wà ní ọwọ́ mi yìí lu odò Naili, omi odò náà yóo sì di ẹ̀jẹ̀.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 7
Wo Ẹkisodu 7:17 ni o tọ