Ẹkisodu 7:3 BM

3 Ṣugbọn n óo mú kí ọkàn Farao le, tóbẹ́ẹ̀ tí yóo fi jẹ́ pé, bí ó ti wù kí iṣẹ́ ìyanu tí n óo ṣe ní ilẹ̀ Ijipti pọ̀ tó, kò ní gbọ́ tìrẹ.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 7

Wo Ẹkisodu 7:3 ni o tọ