Ẹkisodu 8:10 BM

10 Ọba dáhùn pé, “Ní ọ̀la.”Mose bá wí pé, “Bí o ti wí gan-an ni yóo rí, kí o lè mọ̀ pé kò sí ẹlòmíràn tí ó dàbí OLUWA Ọlọrun wa.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 8

Wo Ẹkisodu 8:10 ni o tọ