Ẹkisodu 8:13 BM

13 OLUWA ṣe ohun tí Mose fi adura bèèrè, àwọn ọ̀pọ̀lọ́ tí wọ́n wà ninu gbogbo ilé, ati ní àgbàlá, ati ní gbogbo oko sì kú.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 8

Wo Ẹkisodu 8:13 ni o tọ