Ẹkisodu 8:19 BM

19 Àwọn pidánpidán náà sọ fún Farao pé, “Iṣẹ́ Ọlọrun ni èyí.” Ṣugbọn ọkàn Farao le, kò sì fetí sí ọ̀rọ̀ wọn gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti sọ tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 8

Wo Ẹkisodu 8:19 ni o tọ