25 Farao bá pe Mose ati Aaroni, ó ní, “Ẹ lọ rúbọ sí Ọlọrun yín, ṣugbọn ní ilẹ̀ yìí ni kí ẹ ti rú u.”
Ka pipe ipin Ẹkisodu 8
Wo Ẹkisodu 8:25 ni o tọ