27 A níláti lọ sinu aṣálẹ̀ ní ìrìn ọjọ́ mẹta kí á sì rúbọ sí OLUWA Ọlọrun wa gẹ́gẹ́ bí ó ti pa á láṣẹ fún wa.”
Ka pipe ipin Ẹkisodu 8
Wo Ẹkisodu 8:27 ni o tọ