Ẹkisodu 8:8 BM

8 Nígbà náà ni Farao pe Mose ati Aaroni, ó ní, “Ẹ bẹ OLUWA kí ó kó ọ̀pọ̀lọ́ kúrò lọ́dọ̀ èmi ati àwọn eniyan mi, n óo sì jẹ́ kí àwọn ará Israẹli lọ rúbọ sí OLUWA.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 8

Wo Ẹkisodu 8:8 ni o tọ