Ẹkisodu 9:15 BM

15 Kí ó ranti pé, bí òun OLUWA ti nawọ́ ìyà sí òun ati àwọn eniyan rẹ̀, tí òun sì ti da àjàkálẹ̀ àrùn bò wọ́n; òun ìbá ti pa wọ́n run kúrò lórí ilẹ̀ ayé,

Ka pipe ipin Ẹkisodu 9

Wo Ẹkisodu 9:15 ni o tọ