Ẹkisodu 9:34 BM

34 Ṣugbọn nígbà tí Farao rí i pé òjò ti dá, ati pé yìnyín ati ààrá ti dáwọ́ dúró, ó tún dẹ́ṣẹ̀, ọkàn rẹ̀ tún le, ati ti àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 9

Wo Ẹkisodu 9:34 ni o tọ