Ẹkisodu 9:8 BM

8 OLUWA sọ fún Mose ati Aaroni pé kí wọn bu ẹ̀kúnwọ́ eérú bíi mélòó kan ninu ẹbu, kí Mose dà á sí ojú ọ̀run lójú Farao,

Ka pipe ipin Ẹkisodu 9

Wo Ẹkisodu 9:8 ni o tọ