Ẹkisodu 1:18 BM

18 Ọba Ijipti bá pe àwọn agbẹ̀bí náà, ó bi wọ́n pé, “Kí ló dé tí ẹ fi ń dá àwọn ọmọkunrin tí àwọn Heberu bí sí?”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 1

Wo Ẹkisodu 1:18 ni o tọ