19 Wọ́n dá Farao lóhùn pé, “Àwọn obinrin Heberu yàtọ̀ sí àwọn obinrin Ijipti. Wọ́n lágbára, wọn a sì ti máa bímọ kí á tó dé ọ̀dọ̀ wọn.”
Ka pipe ipin Ẹkisodu 1
Wo Ẹkisodu 1:19 ni o tọ