Ẹkisodu 1:6 BM

6 Nígbà tí ó yá, Josẹfu kú, gbogbo àwọn arakunrin rẹ̀ náà kú ní ọ̀kọ̀ọ̀kan títí tí gbogbo ìran náà fi kú tán.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 1

Wo Ẹkisodu 1:6 ni o tọ