7 Ṣugbọn àwọn arọmọdọmọ Israẹli pọ̀ sí i, wọ́n di alágbára gidigidi, wọ́n sì pọ̀ káàkiri ní ilẹ̀ Ijipti.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 1
Wo Ẹkisodu 1:7 ni o tọ