Ẹkisodu 10:21 BM

21 OLUWA bá sọ fún Mose pé, “Gbé ọwọ́ rẹ sókè sí ojú ọ̀run, kí òkùnkùn lè ṣú bo gbogbo ilẹ̀ Ijipti, òkùnkùn biribiri tí eniyan fẹ́rẹ̀ lè dì mú.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 10

Wo Ẹkisodu 10:21 ni o tọ