Ẹkisodu 10:22 BM

22 Mose bá gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè sí ojú ọ̀run, òkùnkùn biribiri sì ṣú bo gbogbo ilẹ̀ Ijipti fún odidi ọjọ́ mẹta.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 10

Wo Ẹkisodu 10:22 ni o tọ