Ẹkisodu 11:2 BM

2 Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé kí olukuluku tọ aládùúgbò rẹ̀ lọ, ati ọkunrin ati obinrin wọn, kí wọ́n lọ tọrọ nǹkan ọ̀ṣọ́ fadaka ati ti wúrà.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 11

Wo Ẹkisodu 11:2 ni o tọ