Ẹkisodu 11:3 BM

3 OLUWA jẹ́ kí àwọn eniyan Israẹli bá ojurere àwọn ará Ijipti pàdé, ati pé àwọn ará Ijipti ati àwọn ẹmẹ̀wà Farao ati àwọn eniyan rẹ̀ ka Mose kún eniyan pataki.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 11

Wo Ẹkisodu 11:3 ni o tọ