Ẹkisodu 12:33 BM

33 Àwọn ará Ijipti bá ń kán àwọn eniyan náà lójú láti tètè máa lọ. Wọ́n ní bí wọn kò bá tètè lọ, gbogbo àwọn ni àwọn yóo di òkú.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 12

Wo Ẹkisodu 12:33 ni o tọ