Ẹkisodu 12:34 BM

34 Àwọn eniyan náà bá mú àkàrà tí wọ́n ti pò, ṣugbọn tí wọn kò tíì fi ìwúkàrà sí, wọ́n sì fi aṣọ so ọpọ́n ìpòkàrà wọn, wọ́n gbé e kọ́ èjìká.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 12

Wo Ẹkisodu 12:34 ni o tọ