35 Àwọn eniyan náà ṣe bí Mose ti sọ fún wọn, olukuluku wọn ti tọ àwọn ará Ijipti lọ, wọ́n ti tọrọ ohun ọ̀ṣọ́ fadaka ati ti wúrà ati aṣọ.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 12
Wo Ẹkisodu 12:35 ni o tọ