16 Ẹ̀rù jẹ̀jẹ̀ ati jìnnìjìnnì ti dà bò wọ́n,nítorí títóbi agbára rẹ, OLUWA,wọ́n dúró bí òkúta,títí tí àwọn eniyan rẹ fi kọjá lọ,àní àwọn tí o ti rà pada.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 15
Wo Ẹkisodu 15:16 ni o tọ