17 O óo kó àwọn eniyan rẹ wọlé,o óo sì fi ìdí wọn múlẹ̀ lórí òkè mímọ́ rẹ,níbi tí ìwọ OLUWA ti pèsè fún ibùgbé rẹ,ibi mímọ́ rẹ tí ìwọ OLUWA ti fi ọwọ́ ara rẹ pèsè sílẹ̀.
Ka pipe ipin Ẹkisodu 15
Wo Ẹkisodu 15:17 ni o tọ